Awon ololufe meji yii lati ilu Cameroon ko ye e jọ aye loju pẹlu bi ina ife won se n jo bulabula leyin aimoye odun ti won ti so jigi papo. Awon toko-taya ti won je Matinke ati Dongare ni awon kan ri ti won tun tenu bo ara won lenu ni gbangba. E ri wi pe ife dun gan-an.
0 comments:
Post a Comment