Rasaq Olayiwola ti gbogbo eniyan mo si Ojopagogo se iranti iyawo re to ti silebora. Ki Edua oke ba wa dele fun eni to lo. Atejade Ojopagogo ni yii nisale:
"Eni ba magbe ba mi daro aro, eni Maluko ko ba mi daro osun, eni ba mojopagogo latibere wa ko ba mi daro aya rere to lo. This woman is my late wife FUNMILAYO AKANKE OLAYIWOLA, She left us 16 years ago 18th of May 2000. she was an actor, singer, dancer, caring mother, lovely and supportive wife.
Omo Adiba,
Omo Inawole,
ogi oye oro, omo oyediran.
ORUN 'RE O. "
Omo Adiba,
Omo Inawole,
ogi oye oro, omo oyediran.
ORUN 'RE O. "
0 comments:
Post a Comment