Ma fe ki e farabalẹ ka
sitori obirin ti oko rẹ fi bileedi ge ori omu rẹ, ti iyawo naa si tun gbe pelu
iru okunrin bẹẹ fun odindi odun mẹfa. Lopa igba, ni oko rẹ yoo so mọle bi aja
ko to fi tipatipa ba lopo. Ohun to tun panilerin ninu alaye obirin naa ni wi pe,
o ni maanu naa feran oyan mimu pupo ju. O ni le mu oyan fun wakati meta ti yoo
si gbagbe sun lo sibe. Kii se awada, kii si sere, aimoye orisiirisii nnkan ni
awon obirin n koju lowo okunrin alailero, a fi ku Olorun saanu awon obirin.
Ori instagram ni mo ti da
itan naa ko wa fun yin.
0 comments:
Post a Comment