To ba je wi pe Samuel Okwaraji n be laye, o ni yii ni ko ba pe omo odun mejilelaadota (52). Sugbon iku seka, iku doro, iku o je ki Okwaraji o logba pe titi. Ojo kokandilogun osu karun-un odun 1964 ni won bi Okwaraji. Ojo kejila osu kejo odun 1989 lo dagbere faye leni odun marundinlogbon (25).
Ki Edua oke ba wa dẹlẹ fun un.
0 comments:
Post a Comment