Orin:
“Omo ooo
E e pẹ ẹ dagba
Kekere jojolo mo bọmọ
mi
Omo ooo
E e pẹ ẹ dagba”
Orin ope lo gba
enu Sohie Momodu pelu bi ọmọ rẹ, Imade, to bi Dafidi Adeleke ti gbogbo eniyan mo si Davido se pe odun kan
loni. Edumare je ki omo naa dagba-dogbo ko si gbe ile aye se ohun rere. Awon ti
won reti ayọ ọmọ, Baba mimo gbo adura won. Ki o si fi orin ope
si won lenu.
Davido ati Sophie |
0 comments:
Post a Comment