Smiley face

Aare Buhari ti wa lori idubulẹ Aisan bayii


Iwe iroyin PREMIUM TIMES ti gbe sita lonii wi pe, aisan ti da Aare Muhammadu Buhari gunlẹ bayii nile ijoba apapọ to wa niluu Abuja. 

Aisan yii lo ni i se pẹlu kokoro kan ti n yọ baba lẹnu ninu eti. Kokoro eti si ni ko je ko le lọ si awon ipade kan to ti n yẹ ẹ lẹ lẹnu ọjọ bi meta sẹyin.

Gẹgẹ bi ohun ti a gbọ, aisan naa ko jẹ ki Buhari gbọran daada mọ bayii, eleyii to si n fa irora nla fun un ninu eti.

Awon onimosegun alaso funfun ti kun inu Aso Rock bayii lati se itoju baba. 

Adura wa ni wi pe, Oba oke yoo da alaafia pada si i ara rẹ. amin


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment