Alaaja se ololufẹ rẹ loge labẹẹle Olayemi Oniroyin 6/02/2016 05:21:00 pm Iroyin Edit Awon gbeborun kan ni won kofiri obirin yii nibi o ti n ba ọkọ rẹ gerun. Awon kan ni oseese ko jẹ ọrọ aje Naija lo mu onikaluku ma dọgbọn si labẹẹle. Sugbon ka ma parọ, Alaaja yii mọrun ge gan-an ni sa, a bi ẹ ri bo se mu kilipa dani ni? Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Olayemi Oniroyin RELATED POSTS Gani Adams náà tí kàwé gboyè ni LAS...Meji nínú àwọn olè Ofa tí de òpin ì...Boko Haram gbiyanju lati fẹ̀mí ṣòfò... Alaaja se ololufẹ rẹ loge labẹẹle Reviewed by Olayemi Oniroyin on 6/02/2016 05:21:00 pm Rating: 5
0 comments:
Post a Comment