Smiley face

Awon foto Kola Olootu nibi iwuye rẹ gẹgẹ bi BAASORO ILE YORUBA

Lọjọ Isegun to kọja (31-05-16), Olubadan ile Ibadan, Oba Saliu Adetunji, jawe oye tuntun le gomina ẹgbẹ FIBAN nigba kan ri, Otunba Kola Olootu omo Adabanija lori gẹgẹ bi Baasọrọ ilẹ Yoruba. E le kan iroyin naa NIBI.

Awon foto ayeye naa ni yii gẹgẹ bo ti lọ




Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment