E wa wo ohun ti won se fun Ooni Ojaja nigba to fe mu omi niluu Amerika Olayemi Oniroyin 6/22/2016 07:05:00 pm Asa Yoruba , Isese Yoruba Edit Awon aworan Ooni Ogunwusi niyii ni Library of CONGRESS, nibi won ti da lola pelu ami-eye. Sugbon nigba ti baba fe gbe nnkan senu, won ni eewo ni, enikeni ko gbodo ri Ooni nibi to ti n jeun tabi mu omi. Orisun foto: Tunde Alabi Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Olayemi Oniroyin RELATED POSTS Ọjọ́ kẹwàá ni Timi Ẹdẹ ṣe ọdún kẹwà...Olori Memunat tí bí ìbejì láàfin Ọb...Àwon foto láti ibi ayẹyẹ Ọdún Ajé n... E wa wo ohun ti won se fun Ooni Ojaja nigba to fe mu omi niluu Amerika Reviewed by Olayemi Oniroyin on 6/22/2016 07:05:00 pm Rating: 5
0 comments:
Post a Comment