Ka to rerin, o dinu igbo. Ka to refon, o tun dori odan. Ka to ri Muhammad Ali tun doju ala.
Muhammad Ali, elese ribiti ti n gbeni mewaa subu, ti silebora bi aso.
Odun 1942 ni won bi niluu Amerika ko di wi pe o faye sile lojo keta osu kefa odun 2016.
Apapo idije ija esekikan bi mokanlelogota (61) lo ja nigba aye re, eleyii to si je wi pe, marun-un pere lo padanu.
0 comments:
Post a Comment