Se lotito ni wi pe ko si ile iwosan to koju osuwon ni Naija to le se itoju awon adari wa? Enikan ti n je Odolaye Aremu lori FACEBOOK lo gbe eleyii jade:
"Àyà mi wu, ó'n dún mi. Ìyá à mi ba mi fi Ìyé kan epo sii".
My chest was inflamed, and it hurt. My mother dripped palm oil on it with the end of a chicken feather, just to soothe me.
"Etí ń'dun Buhari, o si j'oun pe etí ohun ti di. Ìyá re to o lee ba fi ìyé Eyelé ròó si ti ku tipé. Ilé ìwòsàn kan o si si ni gbogbo orílèèdè wa ti o lee si eti to ti di gbáko! Buhari ba ya sa gba ilu oba lo!"
Edumare dakun ba wa kan epo si eti Olóríoko wa to ti di gbako!"
0 comments:
Post a Comment