Gbajugbaja akoroyin ayelujara, Linda Ikeji, tun ti ko sinu wahala mii bayii. Ninu iroyin to te wa lọwọ, agbejọro kan niluu Eko, Olumide Babalola, la gbo wi pe o fẹsun kan sisi naa latari bo se se afihan awon foto rẹ kan lori itakun agbaye oniroyin naa pelu awon iroyin kan to nii se pelu idaran.
Agbejoro naa ri atejade obirin naa gege bi ibaniloruko jẹ eleyii ti won ti fesun kan bayii pelu owo itanran N50M ti won ni omobirin naa yoo san fun ibaniloruko je naa.
Sugbon sa, ẹjọ naa si wa niwaju onidajọ Hon. Justice O.H. Oshodi ti n jokoo nile ẹjo to gaju lo to wa nipinle Eko.
0 comments:
Post a Comment