Oba alawada meji: Sanyeri gbena woju Mr. Ibu Ola Daviva 6/14/2016 05:04:00 pm Amuludun , Ere Edit Ogbontarigi alawada onifiimu Yoruba, Sanyeri ati MR. Ibu to je okan gboogi laaarin awon alawada fiimu onigeesi ti Nollywood Naijiria ti setan lati gbe sinima tuntun kan jade bayii. Ohun ti a gbo ni wi pe, fiimu naa ko ni pe jade. E ku oju lona! Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Ola Daviva RELATED POSTS Oba alawada meji: Sanyeri gbena woju Mr. Ibu Reviewed by Ola Daviva on 6/14/2016 05:04:00 pm Rating: 5
0 comments:
Post a Comment