Ooni Ogunwusi gbayi niluu Amerika Ola Daviva 6/11/2016 07:16:00 am Asa Yoruba Edit Laipe yii lakede irin-ajo Ooni Ojaja siluu Amerika. Nibayii, Arole Oodua ti bale silu Amerika. Terinteye si ni awon omo Oodua ti won gbe niluu Amerika fi tewo gba Ooni Enitan Adeyeye Ogunwusi ati aya re niluu Amerika. Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Ola Daviva RELATED POSTS Ooni Ogunwusi gbayi niluu Amerika Reviewed by Ola Daviva on 6/11/2016 07:16:00 am Rating: 5
0 comments:
Post a Comment