Aimoye ero witiwiti ni won surubo Ooni Ile Ife, Oba Adeyeye Enitan
Ogunwusi Ojaja II ati aya re, Olori Wuraola Ogunwusi, ni papako ofurufu
Murtala Muhammed to wa niluu Eko ni akoko ti n gbera lo si ilu Amerika.
Ohun ti a gbo ni wi pe, Ooni Ojaja II fe lo se abewo si awon omo Yoruba ti won gbe lawon orileede to wa lapa ariwa Amerika.
0 comments:
Post a Comment