Smiley face

Se iwa arifin ni minisita wu si Alaafin Lamidi?

Minisita fun ibanisọrọ, Barr. Adebayo Shittu se abẹwo si aafin Oba Lamidi Olayiwola Adeyemi III niluu Oyo. Bi o tilẹ jẹ wi pe minisita tẹ lati ki alaafin, se asa Yoruba ko so wi pe, o pa dandan fun minista lati si fila lori ni?

Ohun to koju senikan, eyin lo ko si elomii. Eyin ọjọgbọn, ki lẹ ri si i?

Ninu iroyin mii, mo gbọ wi pe Barr. Adebayo Shittu ti n gbe awon igbese kan labenu lati di gomina ipinle Oyo lodun 2019.




Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment