O jo bi awada sugbon ki i sawada rara. Oju lalakan fi n sori bayii.
Alufa ijo yii ni foto re ti di torofokale bayii lori ayelujara nibi to ti n waasu pelu bajinatu oloju ina legbe re.Erkk
Sugbon sa, a pada gbo wi pe okan ninu omo ologun ni pasito naa loke oya nibi won ti koju Boko Haram.
0 comments:
Post a Comment