Smiley face

Toyin Aimakhu si n wa oyinbo ti yoo fi se ade ori gege bi oko

Lati igba ti Toyin Aimakhu ti ko Adeniyi Johnson sile, ti Seun Egbegbe naa tun ja segbe kan, ni omobirin naa ti seleri wi pe, oun ko tun ni pada se misteki lati fe eniyan dudu mo laye oun.

Lati igba yii si ni Toyin Aimakhu, omo ipinle Edo, ti won bi lodun 1984, ti bere si fo lo silu Amerika ju ti ateyin wa lo.

Awon kan ni o seese ko je lara igbiyanju re lati tete ri oyinbo akata fe lo fi n rin awon irin-ajo naa.

Sugbon sa, adura wa ni wi pe, Olorun yoo se ona re nire. Ase
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment