Ti oju ba n gun eniyan tabi ti oju naa ba n su, bayii ni e se le se iwosan fun oju naa
E wa oyin gidi- ogidi oyin to je ojulowo, e dapo mo ogeere epo pupa.
E ma mu sibi ijeun meta lojumo.
Bakan naa, e gbiyanju lati ma je carrot, water melon ati eyin water melon naa papo moo fun osu kan.
Ni agbara Olorun to daye ati orun, gbogbo arun oju naa yoo salo lai pada wa.

0 comments:
Post a Comment