Omokunrin to de fila pupa ni won seku pa |
Omokunrin omo ile iwe Ifafiti ipinle Imo, to je okan lara awon omo egbe okunkun, ni won ti seku pa lana bayii ode yii (2/08/16) niwaju ile iwe won.
Ohun ti a gbo ni wi pe, ija kan ti n waye laarin awon iko meji egbe okunkun naa saaju. Pipa ti egbe kan si pa omo egbe keji je gbigbesan latari isele to ti se saaju.
Iru ipo le lero wi pe awon obi omo yii yoo wa bayii?
0 comments:
Post a Comment