Ope o! Oba Goriola Oseni ti bo ninu igbekun Olayemi Oniroyin 8/07/2016 09:30:00 am Iroyin , Isese Yoruba Edit Oniba ti Iba, Oba Goriola Oseni ti awon kan gbe salo ni won ti pada tu sile bayii . Komisanna awon olopaa tilu Eko, Ogbeni Fatai Owoseni lo so eleyii di mimo lojo Abameta [6-08-16] to koja yii. Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Olayemi Oniroyin RELATED POSTS Oluwo tí ilu Iwo ti padà pelu ara t...Yorùbá Ni Tòótọ́: Yorùbá kò ní pẹ t...Lọ́jọ́ tí wọn fi Femi Branch jẹ Jag... Ope o! Oba Goriola Oseni ti bo ninu igbekun Reviewed by Olayemi Oniroyin on 8/07/2016 09:30:00 am Rating: 5
0 comments:
Post a Comment