Smiley face

Iyawo sa oko re lada pa nitori owu jije

Arabirin Oluwakemi Etu yii la gbo wi pe o fi ada sa oko re, Kehinde Etu, pa latari wi pe o fe iya mi i le e.

Ijebu-Ode ni isele buruku naa ti waye. Ohun ti a tile gbo ni wi pe, omobirin naa koko gbiyanju lati ba oko re lajosepo ko to ran lo sorun osan gangan.

Agbenuso fun ile ise olopaa ipinle Ogun, ASP Abimbola Oyeyemi, jeri si isele naa. Bakan naa ni won ni iwadii si n tesiwaju lori esun ti won fi kan Oluwakemi.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment