Smiley face

Naija@56: Mo si gbagbo ninu Nigeria

Mo gbagbọ wi pe ile to wo le di kikọ.
Mo gbagbọ wi pe Naija tun le pada di aji-sebi-ọyọ fun gbogbo ile adulawọ yoku.
Mo gbagbọ wi pe ìgbà kan bọ;
Ẹni lo mẹsi ko ni loun jaye mọ.
Tori tẹru tọmọ ni o ni lágbàlá.
Mo gbagbọ ninu àṣà wa.
Mo gbagbọ ninu itan awon akọni wa.
Mo gbagbọ wi pe Naija tun le pada mo ke.
Mo gbagbọ ninu orile mi, NIGERIA.


Happy Independence Day
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment