Akoba kekere ko ni ọlaju mu wọle, bakan naa ni aimoye anfaani ni olaju mu wole. Boya akoba tabi anfaani, o ni i se pẹlu iha ti onikaluku ko si olaju to de.
Awon kan ko rise sẹ, nigba ti awon kan di olowo ojiji latari olaju. Alaye ọrọ ti mo se wa NIBI.
Bakan naa ni mo tun so nipa ona abayo lati mu ọjọ ale wa dun nipa isuna owo. Mo dupe fun gbogbo awon ti won se atileyin fun eto mi, GBEDEMUKE, lati kesejari. Gbogbo wa la ma ri taja se. Ase.

Download
0 comments:
Post a Comment