Awon Yoruba bo, won ni a-pe-ko-to-je ko ni jebaje laelale. Iru ife ati atileyin ti oko Funke, JJC, fihan oserebirin naa je ohun to jo awon eniyan loju. Paapa ju lo, nibi eto afihan sinima re tuntun, Jenifa in London, eleyii to n lo lowo ni UK.
Bi ike ni oko re duro tii leyin eleyii to n fun Jenifa ni koriya ati idunnu. E tun pade Jenifa ni Lighthouse to wa ni Camberwell lonii (6-11-016) nibi ti Sir Shina Peter yoo ti ma gbe Afro-juju soke fun awon ti Sulia Ayetoro kan.
#JenifaInLondon
E wo ohun ti awon eniyan so NIBI
0 comments:
Post a Comment