Smiley face

O ti pẹ ti Seun Egbegbe ti n ja wa lole - Computer Village lo so bee

Seun Egbegbe
Nibayii, awon ara ọja Compter village ti n pe fun idajọ ododo lati owo ijoba. Won ni igba akoko ko ni yii ti Seun Egbegbe ti n wonu oja naa wa ja won lole to si n muje.

Sugbon Olorun lo ni ki palaba re segi lote yii. E le ka ekunrere iroyin naa lori ate iroyin BRAODWAYAFRICA ti won se abewo sinu oja naa

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment