Olamide |
Ẹnu onirọ
aye lati gbọ
wi pe Amọkẹ
ò sọmọọre.
Ẹnu onibajẹ
lasan lati gbọ
wi pe Olamide ò seniyan pataki.
Irọ
lasan la ba lọwọ
onisẹ
dudu aye, aya Oladele sọmọluabi
pupọ.
Orekelẹwa
ti n dan bi egbin lọjọkọjọ
Iwalẹwa
ọmọluabi
ti o labuku.
Oya, ẹ
sare tete kẹ
ẹ wi f’Alara
Ẹni o gẹshin
funfun ni kẹ
ẹ ran lọle
Ajero
Ẹ ni Olamide ti le
lọdun,
ọpẹ
ni f’Oluwa ọba.
Ẹni Oluwa Ọba
dasi lawa n ba yọsẹsẹ.
Adura mi ko pọ
rara, Aya Oladele maa gbọ...
Ire owo, ọmọ,
ayọ,
ati ẹmi
gigun lemi n bẹ Eledumare ko fi ta ọ lore.
Idunnu, igbega
ati alaafia lemi n beere lọwọ Yaradu loke.
#HAPPYBIRTHDAY song for U
0 comments:
Post a Comment