Kabiyesi Ooni Oba Adeyeye Ogunwusi Ojaja Keji
Omo Ojaja fidi ote jale
Omo Ayi kiti Ogun
Omo etiri Ogun
Kare o Leyoo aje okun Ooni
Ajere aboju jojo
Oke leyin Moore
O taye so biigba
Omo Laade
Omo Ibi ro
Omoajongbodo
Omo osun meru ti kun
Omo ibi ola ti n wa
Omo Ayikiti
Ogun tiri Ogun
Mo rejana bi oni roko aburo etiri
Omo Degbin
Mo nlo nre igbode Omo Luusi
Omo arugbo-ile igbode abika lorun
Omo o fose foso, komo Olominrin feeru fo
Omo oke mo ri tikun aya sile.
Omo afinju oloja mo ledena meji
Omo afinju oloja mo re pole owu.
wari oore naa ke e momo Olominrin,
Ona na ro mo Ooni ria.
Omo Ekun sun-un birade,
Omo Odelu kan- bi,
Omo opo mefa oo lerunwa
Ade temi efeefa ni ere
Omo bodere agboobon,
Ikoko degbo deru, .
Omo ajongbodo.
Omo Debooye
Omo Giesi ijana
Mo ba Giesi rejana
Mo ba Debooye a repole
Omo igun gbebo – mo re igbode
Omo igun la gba
Omo igun la je
Omo igun kogokogo lorule
Igun ile rin-in gbebo
Akalamagbo ile rin gbo eru titu
Bi 'ha je tan mun tan
Han moke ikole gun
Mosi ikole Yanrin mi obu lode
ibi an ba ti ba'gun
a tii se igun loore
Omo igun aare mo re ipole
Omo igun gbebo igbode nile re
O re more bi oni roko
Ooro lo to rise de
Han magbala sawesu
Han merinla funfun sekeji Adimunia
Bilia oooo
Adimunia Orisa keji
Yesi a bimo re kope I'ooni o Adimunia.
Biila Egberin ekun
Ajalaye elegberin ikere
Egberin ekun naa si koni rise dodo
Adimunia
Erin a fin bi okin
Omo erin gangan ile
Omo erin gangan ode
Omo erin fi mi joye korun mi mo
Omo erin fi mi joye ki ndekun bebe ona yiye
Abu ajana ogbe
Oba Adeyeye seerin oko bi idikun Oloja
Omo Ogunwusi Adefisan Yeuke
Koo ba ti mun'gun koloree
A ore a han
Omo Osun meru tikun
Omo oye ni moore
Maa niso ni gbangba
Omo Abodere
Omo Agboo ibon
Owolomu ero agbada
Omo Ayidina
Omo Ayilubii
Ponpola abeso jingbinni
O dabi oruru laofin
Oni rakun saye
Yesi b'ooni mi wi o
Oke an setile gun
Mo roke etiri
Ojaja mo mi rodi
Tigbo tiju a ke riri Ayidina
Odi ile lo mi ree ni
Abi toko – Ayilcibii
Omo Dodo bi ide
Omo Ayikiti Oba
Etiri Oba ni Moore
Omo Giesi Degbin koko o hanro igbode
koko o hanro
Kan fi wun Ooni seje lori opo
Eran lo jagbagba Omo Olominrin
Ototo Oniyan lo je tomo Giesi
Oni tii goke esinminrin
Ko wi eru segi npa un
Omo alaran orin
Omo erin meji alo
Omo Ologbenla a ridi ire gabo
A riwo obi salejo
Paraka ode igbodo
Ologbenla a ya'mo paara koji
A yidina bi oke
O soko ekiti soko akoko
Oni akoko nbimo de lese oke
O degbo Igbin
O di kaka bi Oni nrogun
Me tete mo wi aje okun lo bi o
Omo Agbedegbede Oyibo
Omo Agbagba orire nso bi eyokunyokun
Opoto nso bi ikan were nile mi
Omo o soro ko sikisiki bose
Omo o soro fese saworo bade
Omo o soro jo somunlele rodo
Omo o soro gbokunrin niyawo
Omo olodun besebese
Oji Oniyan lo bese somi ria ni morire agbada
Agbagba mi so ipete feye je loja ife
Oni gunyan koko ko wi eyin un bu iloni gun
Omundunmudun adofun dekuru ti maa se
Olori mi ta
Alakara mi ta
Oporoporo o nso bi eru isu
Ari tii ala
Ibee ja ibee maa se sabuja re
Omo Onile aran
Mo mi rele mo mi laa sun
Omo Oloju orun O rigbin ninu oko o fi dooro
Omo Akundinrin esa
Omo Igun aare lo bi o omo onitaji
Oni Giesi bi gbogbo ko bi gbogbo
Ke de lade ale lo loyun re
Itupa meta ona ilase
Ikan nse ni ni rora
Ikan gbe itupa mo ni
O wi epo to ni
Omo Nibaayo
Abu iteni mo ba Giesi lo
Omo owa too lukin foba
Omo igun gee ore
Omo igunlade yoko
Gresi modi
Gresi fire gbe lese
Man diro ni Moore
Maa rebi agbon re
Omo Elekole
Oni bimo kan ko yeniyan
O ya jugba eriwo Omo lo
Omo Giesi Omo Debooye
Laroka modi Giesi fire gbe lese
E si un a soloja ko modi korun.
Kare o Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi
Omo baba ria omo Oba Ropo Ogunwusi
Luuyin – Arobaade yeye oro nijesa
Man wi ki Lowa gbe'bi
Man gbegigun
Man wi ki woye gbebi
O gbaraba
Man Feyinkunie Fanimowu gbebi titi o fi de'bokun
Kabiyesi o Ooni Oba Adeyeye Eniitan
Ogunwusi Ade a pe lori bata a pe lese.
Ku o eye re o,
Babatunde Akande Olewa lowo Olesi merindinlogun
Mejo njoko
Mejo salarije
Kabiyesi o.
Omo Ojaja fidi ote jale
Omo Ayi kiti Ogun
Omo etiri Ogun
Kare o Leyoo aje okun Ooni
Ajere aboju jojo
Oke leyin Moore
O taye so biigba
Omo Laade
Omo Ibi ro
Omoajongbodo
Omo osun meru ti kun
Omo ibi ola ti n wa
Omo Ayikiti
Ogun tiri Ogun
Mo rejana bi oni roko aburo etiri
Omo Degbin
Mo nlo nre igbode Omo Luusi
Omo arugbo-ile igbode abika lorun
Omo o fose foso, komo Olominrin feeru fo
Omo oke mo ri tikun aya sile.
Omo afinju oloja mo ledena meji
Omo afinju oloja mo re pole owu.
wari oore naa ke e momo Olominrin,
Ona na ro mo Ooni ria.
Omo Ekun sun-un birade,
Omo Odelu kan- bi,
Omo opo mefa oo lerunwa
Ade temi efeefa ni ere
Omo bodere agboobon,
Ikoko degbo deru, .
Omo ajongbodo.
Omo Debooye
Omo Giesi ijana
Mo ba Giesi rejana
Mo ba Debooye a repole
Omo igun gbebo – mo re igbode
Omo igun la gba
Omo igun la je
Omo igun kogokogo lorule
Igun ile rin-in gbebo
Akalamagbo ile rin gbo eru titu
Bi 'ha je tan mun tan
Han moke ikole gun
Mosi ikole Yanrin mi obu lode
ibi an ba ti ba'gun
a tii se igun loore
Omo igun aare mo re ipole
Omo igun gbebo igbode nile re
O re more bi oni roko
Ooro lo to rise de
Han magbala sawesu
Han merinla funfun sekeji Adimunia
Bilia oooo
Adimunia Orisa keji
Yesi a bimo re kope I'ooni o Adimunia.
Biila Egberin ekun
Ajalaye elegberin ikere
Egberin ekun naa si koni rise dodo
Adimunia
Erin a fin bi okin
Omo erin gangan ile
Omo erin gangan ode
Omo erin fi mi joye korun mi mo
Omo erin fi mi joye ki ndekun bebe ona yiye
Abu ajana ogbe
Oba Adeyeye seerin oko bi idikun Oloja
Omo Ogunwusi Adefisan Yeuke
Koo ba ti mun'gun koloree
A ore a han
Omo Osun meru tikun
Omo oye ni moore
Maa niso ni gbangba
Omo Abodere
Omo Agboo ibon
Owolomu ero agbada
Omo Ayidina
Omo Ayilubii
Ponpola abeso jingbinni
O dabi oruru laofin
Oni rakun saye
Yesi b'ooni mi wi o
Oke an setile gun
Mo roke etiri
Ojaja mo mi rodi
Tigbo tiju a ke riri Ayidina
Odi ile lo mi ree ni
Abi toko – Ayilcibii
Omo Dodo bi ide
Omo Ayikiti Oba
Etiri Oba ni Moore
Omo Giesi Degbin koko o hanro igbode
koko o hanro
Kan fi wun Ooni seje lori opo
Eran lo jagbagba Omo Olominrin
Ototo Oniyan lo je tomo Giesi
Oni tii goke esinminrin
Ko wi eru segi npa un
Omo alaran orin
Omo erin meji alo
Omo Ologbenla a ridi ire gabo
A riwo obi salejo
Paraka ode igbodo
Ologbenla a ya'mo paara koji
A yidina bi oke
O soko ekiti soko akoko
Oni akoko nbimo de lese oke
O degbo Igbin
O di kaka bi Oni nrogun
Me tete mo wi aje okun lo bi o
Omo Agbedegbede Oyibo
Omo Agbagba orire nso bi eyokunyokun
Opoto nso bi ikan were nile mi
Omo o soro ko sikisiki bose
Omo o soro fese saworo bade
Omo o soro jo somunlele rodo
Omo o soro gbokunrin niyawo
Omo olodun besebese
Oji Oniyan lo bese somi ria ni morire agbada
Agbagba mi so ipete feye je loja ife
Oni gunyan koko ko wi eyin un bu iloni gun
Omundunmudun adofun dekuru ti maa se
Olori mi ta
Alakara mi ta
Oporoporo o nso bi eru isu
Ari tii ala
Ibee ja ibee maa se sabuja re
Omo Onile aran
Mo mi rele mo mi laa sun
Omo Oloju orun O rigbin ninu oko o fi dooro
Omo Akundinrin esa
Omo Igun aare lo bi o omo onitaji
Oni Giesi bi gbogbo ko bi gbogbo
Ke de lade ale lo loyun re
Itupa meta ona ilase
Ikan nse ni ni rora
Ikan gbe itupa mo ni
O wi epo to ni
Omo Nibaayo
Abu iteni mo ba Giesi lo
Omo owa too lukin foba
Omo igun gee ore
Omo igunlade yoko
Gresi modi
Gresi fire gbe lese
Man diro ni Moore
Maa rebi agbon re
Omo Elekole
Oni bimo kan ko yeniyan
O ya jugba eriwo Omo lo
Omo Giesi Omo Debooye
Laroka modi Giesi fire gbe lese
E si un a soloja ko modi korun.
Kare o Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi
Omo baba ria omo Oba Ropo Ogunwusi
Luuyin – Arobaade yeye oro nijesa
Man wi ki Lowa gbe'bi
Man gbegigun
Man wi ki woye gbebi
O gbaraba
Man Feyinkunie Fanimowu gbebi titi o fi de'bokun
Kabiyesi o Ooni Oba Adeyeye Eniitan
Ogunwusi Ade a pe lori bata a pe lese.
Ku o eye re o,
Babatunde Akande Olewa lowo Olesi merindinlogun
Mejo njoko
Mejo salarije
Kabiyesi o.
0 comments:
Post a Comment