OHUN TO N FA GBEREBI LARA OBINRIN ATI ONA LATI DENA RE:-
Opolopo okunrin ni ko nife si gberebi lara iyawo won, fun idi eyi opolopo loti bere sini yan ale nita.
AWON OHUN TI A LE RO PE O N FA GBEREBI NIYI:- ti alaboyun ba wa ninu oyun, gberebi le je jade lara e. Ti eyan ba sanra ju ti tele lo, o le fa gberebi, ti omokunrin ba un se ere idaraya ole fa gberebi, ti a ba n lo ipara to n bo ara ohun naa le fa gberebi, tabi ipara toti baje, otun se se ka jogun e lara awon obi wa
ÀWON OHUN TI A LE LO SI GBEREBI NIYI :- aloe vera ati ewe aloe vera na dara lati ma fi pa a lojojumo. Eso cucumber naa dara ka ma fi pa oju gberebi naa.
Ipara kan ti won n pe ni cocoa butter naa dara lati ma fi pa a ni emeji lojumo. Ale lo omi inu eyin naa a o yo yooki inu e kuro, a o wa fi omi inu e pa oju ibi gberebi naa, awa je ki omi inu eyin yen gbe mo oju ibe leyin eyi awa fi omi tutu fo kuro.
A tun le lo olive oil naa, a o gbe olive oil yen kanaa bi gba ta fe din eyin, leyin ti olive oil yen ba gbonan tan awa so kale aje ko tutu dada leyin eyi a ma fi pa oju gberebi naa, e ma si mi gbo ooo ki se ororo gbigbo na lani ke fi para ooo, a le lo osan wewe naa a o ge si meji, a o maa fi pa oju ibi ti gberebi yen wa fun bi iseju mewa leyin naa a wa fi omi to lo woro fo kuro, a lero pe gbogbo ohun ti a so yii lo ye wa yeke-yeke e ma gbe omo oba fun osun lori awon alaye ti a so ooo.
Eyin obinrin etoju ara yin ke le ba ma da awon oko yin lorun ni gbogbo igba, ile alayo gbogbo wa koni di ile ekun lase olorun. Amin.oooo.
Orisun: Olùkó Èdè Yorùbá Arb
0 comments:
Post a Comment