Eleyii ni won fi n sami ojo ti won da United Nations Radio sile ti n se ojo ketala osu keji dun 1946. Akori ajodun odun eyi si in "Radio is you" (Iwo ni redio).
Pataki redio ko kere rara lawujo. Iwasaye re si bere nipa akitiyan lati je ki awon eniyan igberiko mo awon nnkan ti n lo lawujo won.
Redio rorun lati gbo fun ara ilu, ki i na eniyan loogun bakan naa ni i ma so ede ti awon eniyan gbo julo- ede ibile.
Sugbon sa, se a le soro redio lai ma so nipa awon olopolo pipe ti won n pede ara lori redio.
E daruko awon sorosoro ori redio ti eyin n gbo, ti e si n gbadun, lati fi se koriya latari ise takuntakun ti won se. https://m.facebook.com/groups/250287078355942?view=permalink&id=1455146264536678
0 comments:
Post a Comment