Inu awon ololufe won ko dun si isele yii, nitori igbeyawo ti omo ti wo ni.
Oni, Feb 5, ni ojo ibi awon mejeeji. Saheed pe eni aadota Odun (50) nigba ti aya re nigba kan ri pe eni odun mejidinlaadota (48) lonii kan naa. A ki won ku ojo ibi, igba odun, odun kan ni. Ase.
0 comments:
Post a Comment