Aimoye awon olopolo eda to wa layika wa ni won ko ba ti gbe ogo Naijiria ga bi ilu China, Japan ati awon ilu ti won ko lola tele sugbon ti won ti n gbe igbe aye irorun bayii.
Ni ilu Onitsha, omokunrin yii, eni odun merindinlogun (16), lo se ohun idana eleyii to n lo eedu, ina monamona, bakan naa lo tun un lo batiri.
Ti iru omo bayii ba ri iranlowo to peye, o daju wi pe opolo re yoo tun sise iyanu ti aye ko lero.
0 comments:
Post a Comment