Gege bi agba olorin, awon kan so wi pe, o ni lati ni ohun ti Ayinla ni lokan tabi to dimu lokan re nipa agbara ti orin ni ko to le pe iru ede bee jade.
" Eyin ara, ki le n forin pe?"
Fun awon ti won je ololufe orin Egunmogaji, e se akiyesi wi pe, o ti fi igba kan se alaye bi orin se wa si ile aye eleyii ti asiri naa si farasin fun awon onise alakada titi di akoko yii.
Bakan naa, Fela Anikulapo se alaye orin gege bi emi airi eleyii ti ko se fojuri ti ko si see fi sere.
Orin awon agba onkorin kun fun ogbon, aditu, imo to jinle ati iriri to laamilaaka.
Orisii awon alaye yii si le koko bi oju eja fun eni ti ko motun yato sosi nile orin.
Sugbon mo ti lo foro lo awon agba ki n le gbon bi Ifa, ki n si moran bi opele.
E pade mi Lori eto #OrinAgba to kale sori telifisan @tiwantiwa247 [gotv Channel 111]. #Thursdays
E ku oju lona!
0 comments:
Post a Comment