Smiley face

Abadofin lati fi ofin de ila kiko ti n gbona felifeli nile igbimo asofin

Image result for triber mark in africa 

Fun igba keji, ile igbimo asofin agba to kale siluu Abuja ti ka abadofin eleyii to n pe fun ifofin de ila kiko ni ile Nigeria.

Abadofin tuntun yii ti Senato Dino Malaye n se agbateru re lo ti bere si fa orisiirisii awuyewuye laaarin awon asofin naa.
 

Awon kan gba wi pe asa ile wa ni eleyii ti agbonju ba lowo awon babanla wa. Ninu alaye won naa ni won ti se alaye ila kiko gege bi ami kan pataki ti won fi mo idile tabi ibi ti enikan ti se wa tabi orisun eni naa.
Image result for triber mark in africa

Ju gbogbo re lo, won ni a ko le sai tun se agbeyewo ojuti ti ile kiko n mu wa fun eni ti ila mbe loju re. Yato si wi pe ila kiko ko ba ara sore, won ni a maa mu edun okan ba omo ni kilaasi laaarin awon akegbe re yoku ti ko kola soju. 


Koda, won tun le fi iru omo bee se yeye nipa fi fun ni oruko orisiirisii bi tiger tabi oloju railway.

E je ka tun wo atotonu Ogbeni Dino Melaye nigba ti apero naa waye
Image result for triber mark in africa

“The irony of these marks is that it makes victims subjects of mockery by friends. Imagine someone being called a tiger simply because of the thick cheeks resulting from facial marks.

These people have been subjected to different reactions. Some have lamented the marks that are bequeathed on them as generational inheritance.Many have cursed the day which this dastardly act was performed on them.

Many of the grown adults have confessed that the most terrific debacle of their lives is their tribal marks. Some have become eunuchs because of this stigma. Imagine a boy in the class of 25 pupils carrying a tribal mark. His mates will call him the boy with the railway line.

They are emblems of dis-figuration. Some of them have developed low self-esteem and most times treated with scorn and ridicule including rejection by the female folks.

The reactions of people who interact with them say it dampens and lowers their spirit, Ogbe Melaye salaye bee.










Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment