Dino Melaye ti gbe Sahara Reporters lo si ile ejo. N5b lo fe gba gege bi owo itanran Olayemi Oniroyin 3/23/2017 06:03:00 pm Oro Oselu Edit Senator Dino Melaye ti gbe ile ise iroyin Sahara Reporters lo si ile ejo latari esun ibaniloruko je ati iparomoni. Ti e ko ba gbagbe, ile ise iroyin yii lo gbe jade wi pe, Senato ti n soju iwo oorun Kogi ko niwe eri. Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Olayemi Oniroyin RELATED POSTS Dino Melaye ti gbe Sahara Reporters lo si ile ejo. N5b lo fe gba gege bi owo itanran Reviewed by Olayemi Oniroyin on 3/23/2017 06:03:00 pm Rating: 5
0 comments:
Post a Comment