Smiley face

Ise tiata ati kadara: Ayo lo ma jasi

Iwe itan ere onise (tiata) dabi kadara eda. Ibere le koro bi ewuro sugbon ohun to daju ni wi pe, akosile ko ni tase. Isoro eda ki i se titi aye.

Ipenija oni a si ma silekun fun ogo ola. Leyin okunkun, imole n bo. Bekun pe dale ayo mbo lowuro. Ire ni Olorun ni fun wa, kadara eda kosi ni tase.

Ayo lo ma jasi.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment