Sugbon gege bi oro awon Yoruba, won ni ojo gbogbo ni tole, ojo kan ni tolohun.
Lati ojo keedogun osu keta odun 2017 ti awon olopaa ti wa gbe omobirin naa, won ko ti fi sile lori esun to seese pelu awon iro ti n pa ninu ise iroyin re titi di oni to je 17-03-2017.
Ni ibere osu yii ni anti naa ni ki n mori wa ki n forun un le. O ni ki awon ile ise ti mo sise fun damiduro nitori iroyin mi ki i se ojulowo. Ko si eebu ati oro idoti ti ko so si mi tan.
Sugbon emi ti fi gbogbo re le Olorun lowo. Onikaluku ni yoo jere ise owo re gege bo ti ye.
0 comments:
Post a Comment