Sugbon nigba to ya, se e mo oro awon okunrin, lo ba yari wi pe oun ko se ileri kankan fun omidan naa.
Aseyinwa-aseyinbo, ohun to sele si okunrin naa ni yii. Won ni o seese ko je omobirin to ja sile lo fi adawon nas kan an.
To ba je wi pe omobirin naa lo wa nidi isele yii, nje eyin ro wi pe ohun to se dara tabi ko dara?
0 comments:
Post a Comment