Smiley face

Yeye Oge ti le lodun: Oyindamola Adegbenro fako yo!

To ba je tewa nini, Oyindamola omo Adegbenro rewa lobirin gidi.

Iwa irele ati omoluabi lo fi deni taye n fe bi oju. Onise tiata to se kowo le lori l'Oyibdamola.

O logbon lori bee nimo re kun fofo bi ataare.

Oni lojo ibi Yeye Oge.
Oni lojo ibi orekelewa ti dani lorun bi eye okin.

Oyindamola, bo ba lo igba odun laye odun kan pere ni won o fi ka fun o lode orun.

#HappyBirthday

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment