Smiley face

E wa wo bi ori se da Ngolo Kante lola

Eda o laropin; ori nikan lo mo eni ti o la lola. Ngolo Kante, omo ilu Mali ti fi igba kan kiri ta omi tutu ri.

Lonii, o wa lara awon agbaboolu ti n gba owo julo niluu England.

#Kadara

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment