Oseese ko je wi pe, Salawa Abeni yoo darapo mo okan lara awon oju ti o maa gbe ileese naa laruge.
Tecno ti lo ka Salawa Abeni mole
Queen Salawa Abeni gba awon asoju ileese Tecno lalejo ninu ile re. Nibi abewo yii ni won si ti fi ebun foonu tuntun taa lore.
0 comments:
Post a Comment