Smiley face

Ajumobi ko kan taanu

Ni iwonba akoko die ti mo de ile aye, awon eko kekere kan wa ti mo ti mo to ma je idunnu fun mi. Lara eko naa ni lati ma reti esan-oore tabi oore lati owo enikan ni pato.

Ti eniyan ba n se eleyii, eni naa yoo se ara re ati si Olorun re nikeyin.

Ti mo ba soore fun eniyan, mi o ki n reti ko san an. Ti eni naa ko ba san yoo fa ibanuje fun mi, ikorira eni naa si le mu mi dese si Oluwa Oba.

E fi igbe aye yin le Olorun lowo, Oun nikan lo le soore otito feda ki i se eniyan. Ti Olorun ko ba si ti ran eniyan lowo, ko si eda to le ran an yan leru.

Okan ninu awon ise ti mo ti se seyin ni yii: https://www.spreaker.com/show/olayemi-oniroyins-show

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment