Awon odaran yii ni won feran lati ma kogun ja awon akekoobirin ni ile won, won yoo gba owo, awon ohun ini won, won tun fi ipa ba won lopo. Sugbon bayii, owo ti te awon meji ninu won.
Awon odaran, ole, afipabanisun meji ni owo te n'Ijagun, Ipinle Ogun
Ojo gbogbo ni tole, ojo kan ni tolohun. Awon odaran, ole, afipabanisun meji kan ni owo ti te bayii ni Ijagun to wa n'Ipinle Ogun.
0 comments:
Post a Comment