Ibanuje ki i yii nnkankan pada, o tun ma n se akoba ni. Ile aye kun fun isoro, sugbon awon olokan lile ati igbagbo ninu aseda ni yoo bori aye. Ma se je ki ohun to n la koja se akoba fun idunnu re. Ma rerin, si ma dunnu, nitori ola re yoo dun joyin lo.
Olayemi Olatilewa ni oruko mi. Awon ore mi niluu India ni won ma pe ni Sultan.
0 comments:
Post a Comment