Pelu ayo ni oniroyin ayelujara naa fi n ba awon ololufe re soro to si n toro idariji fun awon asise re isaaju.
O je ko ye awon eniyan wi pe, alaafia ni oun mu wa bayii ati wi pe ko si ogun ati ija mo laarin oun ati awon ota oun lori ayelujara.
Omobirin to ti fi igba kan gbe ninu Canada tun so wi pe, oun ko ni pe se alaye oun ti oju oun ri ninu ogba ewon ilu Pota lai pe.
A ki Aunty Kemi ku ayo igbala okan re. A gbadura wi pe, igbala re ko ni jabo mo o lowo. Ase
0 comments:
Post a Comment