Leyin opolopo laasigbo ti Mercy Aigbe koju lati odo oko re, Lanre
Gentry, eni to fi ese ba oju omobirin nas je lati ma wulo mo fun un.
Leyin
eyi, ohun ti a gbo wi pe, oserebirin naa gba ilu London lo fun itoju to
peye.
Abajade itoju naa lo pada so oju Mercy di rigindin pada loju awon
ololufe re kaakiri agbaye.
Oro Mercy ni a le fi we ile oba to jo, eleyii to pada fi kun ewa re lopolopo.
0 comments:
Post a Comment