Smiley face

Orisii aisan meji ni awon dokita toju lara Buhari niluu London- Amugbalegbe re lo so bee

Iroyin to lu jade fi ye wa wi pe, ara Aare Muhammadu Buhari ti n pada bosipo daada ati wi pe, ko ni pe pada siluu Naija.

Okan ninu awon amugbalegbe Buhari, eni ti o ni ki won fi oruko bo oun lasiri to soro yii jade ko le so ojo kan pato ti oko Aisha yoo pada wale. "Dokita Buhari nikan lo le so wi pe ki aja4 Buhari gbera ni ojo bayii. Sugbo nipa oye mi, ara Sai Baba ti le kokoko bi eni to mu energy tutaosan."

Amugbalegbe Buhari to ni ki won ma daruko oun yii so gbangba wi pe, orisii aisan meji sanko ni won toju lara PMB eni to ti fi igba kan je aare ologun laaarin odun 1983 si 1985.
Awon aisan naa ni, siso iye nu (ki eniyan ma le ranti ateyinwa daada). Eleekeji ni ki oro maa tase lenu nigba eniyan ba n soro.

Sugbon sa, Aare Muhammadu ti wa ni kampe bayii. Igbakuugba si ni baba le yo wole siluu Naijiria lati ilu London to ti n gba itoju.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment