Arin gini gini w'oja
Olupese Oro Owinrinkinsisi
Olokun Semi Ade
Elegbeje Ado
Bukusa Oro
Alukubeli ti deru bosi
Odudun asode dero
Aje je ki nni o lowo
Aje osu na asebi
Aje ti so eru d'omo
Oosa ni we iya okin
Aje nii weri omo
Onipasan owere
Aje dakun ma na mi ni pasan re ko se naani
A na omo na yeye
Pasan re ko se na ni
Aje nii so ewe dagba
Kos i Oosa taa deyin aje se
Je ki n ri ona
Je ki nri o mulo lati se gbogbo nkan ti no fe se
Ki nri n muse ohun rere
Owo yeri yero okin
Aje o o pomo b'imo oro.
0 comments:
Post a Comment