Se "baba ibeji" ni dokita obirin yii n fowo pa ni?
Foto yii lo ti bere si ni fo kiri ori ayelujara bayii eleyii ti n se afihan dokita ati agbaboolu ni orileede Zambia. Awon kan gba wi pe, ibi to lewu lara omokunrin naa ni omobirin naa n fowo pa...se looto lori bee?
0 comments:
Post a Comment