"Faaji ati isimi ni mo wa," oserebirin Eniola Ajao lo so bee
Sebi won ni omo to ba n sise deede, dandan ko ni asiko faaji, Eniola Ajao, oserebirin onitiata, ti kede isimi re eleyii to lo re e se leyin odi. Osere naa ko ti je ka mo nipa ilu to ti lo re e se faaji gan-angan, sugbon a ni igbagbo wi pe eleyii ko ni pe foju han laipe pe
0 comments:
Post a Comment